Ósun ségésé oóríyá iyun awede kí ó tó wémo Ósun eléyinju
áánu igbómolé obínrin Ósaáyó m'olé Ómómó t'enu m'olé
ayaba bínrin ótóró éfón n'ilé íyá olugbon wón kó gbodó m'oró
íran árésa won kó gbodó m'oró ógbóju óludó tín lu ípésé, ósun
awede wemo wá w'emo re fun wa kó And That's
Óriki Ósun I Can Remember Happy Ósun Ósogbo Festival Y'all
Like i Said Am Proud of My Tradition Y'all . #ÓsunOsogboFestival2021#Tradition#Love